New Music + Lyric  - Oluwadamilola - Ranti Mi Oluwa

New Music + Lyric – Oluwadamilola – Ranti Mi Oluwa || Damilola Olusoji is a fast-rising gospel artist who hailed from Ogun State Nigeria. She’s the writer and composer of the single RANTI MI OLUWA. She’s a songwriter, a song leader, and a dedicated child of God.

Lyrics:

Chorus:
Ranti mi o baba ma gbagbe mi, ranti mi si
rere oluwa mi kojo to lo ooo,
Adani ma gbagbe oba alagbara wa damilola oluwa
k’odun yi to lo.

Solo 1:
Ojo n re bi ana, orun n re bi atiwo, olojo
n’kajo ki gbami ma koja mi,
Ireti pipe o maa
n mokan sare, tete dami lohun kaye le
bami dupe ooo

Solo 2:
Otipe ti mo tin woju re aiye duro won fe
s’eleya mi ooo,
Won ni nibo ni Olorun mi
wa,
Ma se jeki aiye se yeye mi
Mi o lelo miran Olorun sanu fun mi,
Tete bami se
Olorun ojo nlo.

Solo 3:
Mo ti gboju mi soke ayo mi ti de eee,
Bekun pe dale kan ayo n bo lowuro,
Baba oti gbo adura mi o fi dami loju pe ohun yio damilola

Call: damilola oluwa wa semi lologo ooo
Res: Wa damilola oluwa kodun yi to lo

Call: Se temi fun mi ooo baba ma gbagbe
mi ooo / Res

Call:Je karaye bami yo karaye bami jo
ooo/ Res.

Call: Alekun owo alekun omo alekun
omo ohun rere ni mo n fe/ Res.

Call: Ohun gbogbo ni rere ni rere ni mo n
toro/ Res .

Call: Ohun gbogbo ni rere ni rere ni mo n
toro baba / Res .

Call: DAMILOLA oluwa wa se mi lologo
ooo 2× / Res

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here